100% found this document useful (1 vote)
1K views2 pages

Afose Adura Ifa

This document describes how to make an afose, which has several plant leaves, snake parts, and soap. The leaves include fire leaf, nettle leaf, horseweed leaf, and sweet potato leaf. It also includes a snake head, gazelle horn, and coastal soap. The ingredients are pounded together and shaped around the horn with the snake body inside.
Copyright
© © All Rights Reserved
We take content rights seriously. If you suspect this is your content, claim it here.
Available Formats
Download as PDF, TXT or read online on Scribd

You are on page 1/ 2

This is Ifa Afose: Ewe Ina ,Ewe Aragbaa, Ewe Oloyin, Ewe

Esisi, Ori Oka ,Oko oka ,Abe Olola Iwo Igala Ose dudu A oo
gun awon ewe yii pelu ori oka mo Ose dudu,a oo ko sinu Iwo
Igala,A oo fi Abe olola ati Oko Oka gun lori,Ti a ba ti fe e lo,a
oo fi Abe olola ati Oko Oka kan ori ahon, a oo wa pe ofo re
si. This is how the afose is made but It has incantation.I will
write you the incantation and let me write it in Yoruba
language before I will try the translation.
Elemo ni loroo,O de Idaho damureja,Awon Lo sefa fun
Olumose,Yoo koda sete,Yoo mo fenu mu bi abe,Awon Iyami
lolumose,Won ni gbogbo oro ti Orunmila ba n so,won ni ko ni
se,Orunmila ni Iro ni,Oni gbogbo oro ti oun ba n so,Yoo mo
se ni,Won ni bo ni Oro ti Orunmila ba n so yoo ti mo se?
Orunmila ni ki won o lo pa Agbonrin togun toni ole ninu
wa,Won lo pa agbonrin togun toni ole ninu de,Orunmila ni ki
won o kun-un,Oni won yoo ba ole ninu re,Won yoo ba Ila
leyin re,Won kun-un Agbonrin togun toni ole ninu,Won ba ole
ninu re,Won si ba Ila leyin re,Awon Olumose ni haaaaa,Won
ni gbogbo oro ti Orunmila ba n so ni yoo mo se,Won ni tori
Kankan lewe ina jomo,Wara lomokekere bo oko esisi,Ile
kogba,Ona kogba ni sewe aragbaa,Ewe Oloyin kii kohun
Obarisa,Eran toka ba so,enu oka ni ku si,Omo kekere kii je
okigbe,ki abe olola ko mo ran-an,Ori ni agbonrin fi la Igbo
ja,Gbogbo ohun ti ma ba n wi ni ko mo se.A oo wa yo abe
olola yii ati oko oka a oo fi kan ahon. Opari. I will try to do
translation latter
tradução
afose para ifa
folha de fogo
folha de urtiga
folha de arebenta cavalo
folha de batata doce
uma cabeça de cobra
um chifre de gazela
sabão da costa
modo de fazer
pila as folhas
pila a cabeça da cobra
mistura com sabão
adicionar esta mistura ou chifre de gasela
o corpo da cobra deve ficar dentro do chifre
podendo para isso toralo
ofore :
Elemo ni loroo,O de Idaho damureja,Awon Lo sefa fun
Olumose,Yoo koda sete,Yoo mo fenu mu bi abe,Awon Iyami
lolumose,Won ni gbogbo oro ti Orunmila ba n so,won ni ko ni
se,Orunmila ni Iro ni,Oni gbogbo oro ti oun ba n so,Yoo mo
se ni,Won ni bo ni Oro ti Orunmila ba n so yoo ti mo se?
Orunmila ni ki won o lo pa Agbonrin togun toni ole ninu
wa,Won lo pa agbonrin togun toni ole ninu de,Orunmila ni ki
won o kun-un,Oni won yoo ba ole ninu re,Won yoo ba Ila
leyin re,Won kun-un Agbonrin togun toni ole ninu,Won ba ole
ninu re,Won si ba Ila leyin re,Awon Olumose ni haaaaa,Won
ni gbogbo oro ti Orunmila ba n so ni yoo mo se,Won ni tori
Kankan lewe ina jomo,Wara lomokekere bo oko esisi,Ile
kogba,Ona kogba ni sewe aragbaa,Ewe Oloyin kii kohun
Obarisa,Eran toka ba so,enu oka ni ku si,Omo kekere kii je
okigbe,ki abe olola ko mo ran-an,Ori ni agbonrin fi la Igbo
ja,Gbogbo ohun ti ma ba n wi ni ko mo se.A oo wa yo abe
olola yii ati oko oka a oo fi kan ahon. Opari.

observação o afose deve ficar enrolado em pano vermelho

You might also like