Ljewo: Orin Daf.
23:5 Iwo te tabili ounje sile niwaju mi li oju
Awon ota mi,iwo da ororo si mi li ori, ago mi si kun
Akunwosile. Sugbon iwo mi ni iwo o gbega bi iwo
Agbanrere,ororo tuntun li a o ta si mi lori. O. D. 92:10
JERE:5:33-34. Bayi li Oluwa awon omo ogun wi pe awon
Omo Isreali ati awon omo Juda li a jumo pon loju po,
Gbogbo awon ti o ko nwon ni igbekun si di won mu sinsin
Won ko lati jo won lowo lo sugbon Olurapada mi lagbara,
Oluwa awon omo ogun li oruko re ni jija yoo gba ija mi ja, ki
O le mu ile mi simi ki o si mu awon olugbe Babiloni wariri.
KOKOADURA
1. Mo fo gbogbo igbamu okun Elena lori aye mi ni oruko Jesu.
2. Mo fo gbogbo agbara pasiparo lori aye mi nipa ina ni oruko Jesu.
3. Gbogbo ofa airi eyi ton sise ninu ori mi o ya gbina jade ni oruko Jesu.
4. Ori mi o! Gba itusile fun ise rere ni oruko Jesu.
5. Ori ni o! gba irapada kuro labe imuleru ni oruko Jesu.
6. Mo fo gbogbo agbara aale awon aje ninu ori mi ni oruko Jesu.
7. Mo fo gbogbo igbamu ase ibi lori aye mi ni oruko Jesu.
8. Mo fo gbogbo igbamu ogun ti enikeni ti se lodi si ori mi ni oruko Jesu.
9. Mo fo igbamu egun, epe, ayajo, ogede lori aye mi ni oruko Jesu.
10. Mo fo gbogbo igbamu etutu, ati ebo ibi lori aye mi ni oruko Jesu.
11. Mo fo gbogbo igbamu Farao idile lori aye mi ni oruko Jesu.
12. Mo fo gbogbo igbamu ika idile lori aye mi ni oruko
Jesu.
13. Mo fo gbogbo igbamu ti asotele ibi lori aye mi ni
Oruko Jesu.
14. Mo fo gbogbo igbamu ala ibi lori aye mi ni oruko
Jesu.
15. Mo fo igbamu ikuna lori aye mi ni oruko Jesu
16. Mo fo igbamu iku aitojo lori aye mi ni oruko Jesu
17. Mo fo gbogbo igbamu esu odara lori aye mi ni
Oruko Jesu.
18. Nipa eje Jesu, mo fo igbamu majemu orisa lori aye
Mi ni oruko Jesu.
19. Nipa ina, mo fo gbogbo igbamu emi osi lori aye mi
Ni oruko Jesu.
20. Iwo ori mi o, bo aso esi danu ki o si gba ogo tuntun
Ni oruko Jesu.
21. Gbogbo ofa iponju ninu orj mi o ya gbina jade ni
Oruko Jesu.
22. Ori mi o seru, iwo ori mi bo aso eru sile ni oruko
Jesu.
23. Emi Mimo da ororo ise rere simi ni ori ni oruko Jesu.
24. Emi Mimo da ororo ayo simi ni ori ni oruko Jesu.
25. Emi Mimo o da ororo itusile le mi ni ori ni oruko
Jesu.
26. Iwo ori mi gba atunse nipase Emi Mimo ni oruko
Jesu.
27. Oluwa ni olugbe ori mi soke, iwo ori mi gba
Igbesoke orun ni oruko Jesu.
28. Agbada Agbara Emi Mimo, o ya ba le mi lori ni
Oruko Jesu.
29. Emi Mimo da ororo agbara le mi ni ori ni oruko
Jesu.
30. Ogo aye mi dide ki o si ran bil oorun ni oruko Jesu.
31. lwo ori mi gbo ki o si gba; ko iku aitojo ni oruko
Jesu.