7.
Lehin eyi ojo ayo kan mbo,
Awọn mimo yoo jinde ninu Ogo,
Oba ogo y'o si wa larin wọn.
Alleluya!
8. Lat' opin ile lat' opin okun,
Ogunlogon ro wo 'bode Pearli;
Won yin Baba, Ọmọ ati Emi.
Alleluya! Amin
7.
8.
4. ORIN DAFIDI 90
4.
1.
Oluwa iwo ni o tin se ibujoko wa lati 1.
randiran
2.
Ki a to bi awon oke nla, ati ki a to da ile 2.
oun aiye ani lati aiyeraye, iwo ni
Olorun
3.
O so eniyan di ibaje, o si tun wipe e
pada wa eyin omo eniyan
4.
But lo! there breaks a yet more
glorious day;
The Saints triumphant rise in bright
array;
The KING of GLORY passes on His
way. Alleluia!
From earth's wide bounds, from
ocean's farthest coast,
Through gates of pearl streams in the
countless host,
Singing to FATHER, SON and HOLY
GHOST
Alleluia! Amen.
PSALM 90
Lord, thou has been our dwelling place
in a generations.
Before the mountain were brought
forth, or ever thou handst formed
the earth an world, even from
everlasting, thou art God.
3. Though turnest man to destruction;
and sayest, return, ye children of man
Nitoripe igbati egberun odun ba koja, 4. For a thousand years in Thy sight are
li oju re bi ana li o ri, ati bi igba iso kan li
oru
but a yesterday when it is past, and as
a watch the night
5. O'nko won lo bi eni pe ninu isan omi; 5. Thou carries them away as with a
nwon dabi orun ni kutukutu nwon
dabi koriko ti o dagbasoke.
flood; The are asleep: in the morning
they are like grass which groweth up.
soke li asale a ke e lule, o si ro
6. Ni kutukutu o li awo lara, o si dagba 6. In the morning it flouriest, and growth
up; the evening, it is cut down, and
withereth
nipa ibinu re ara koro wa
7. Nitori awa di egbe npa ibinu re, ati 7. For we are consumed by kined anger,
8.
Oti gbe ese wa kale niwaju re, ese 8.
ikoko wa nbe ninu imole oju re.
and thy wrath are we trouble.
Thou hast set our iniquities before
thee, our secret sins in the light of thy
countence