100% found this document useful (1 vote)
4K views2 pages

Ogun Ibile

Uploaded by

yvesgennari
Copyright
© © All Rights Reserved
We take content rights seriously. If you suspect this is your content, claim it here.
Available Formats
Download as DOCX, PDF, TXT or read online on Scribd
100% found this document useful (1 vote)
4K views2 pages

Ogun Ibile

Uploaded by

yvesgennari
Copyright
© © All Rights Reserved
We take content rights seriously. If you suspect this is your content, claim it here.
Available Formats
Download as DOCX, PDF, TXT or read online on Scribd
You are on page 1/ 2

84.

AGBOIBALOPO STD
Elo gbiyanju eleyi wona arun ibalopo lohun sise fun koda boje
atosi oloyun otun sise fun na....
Abu-otoyo, Epakun, Bara nla kan, Kanhun-bilala die, Kegi 2ltr

Sisere:- ema be bara na bi enibe ibepe, emabe epo arare kuro


emayo egusi RE KURO, emawa ha EEPO epakun yen ma bieni
be koko emage kekeke , emako bara tele kegi yen emako
epakule amako obuotoyo si ematifo obuotoyo yen kekeke o
kolewo inu kegi pelu barana kolewo enu kegi yen o, emawa fo
kanhun bilala yen SINU e, emawa lora original OMI OSAN
wewe le lori leyin ijo keta komalo walahi gbogbo arun ibalopo
lohun sise fun koje atosi oloyun yio lo nigbati obafi mato osekan
ARO, OSAN, ale, komalo

1. bara, ewe epin ati osan wewe, kaunbilal, ao se lagbo bi 5min


tio ba ti tutu ao da oyin die si,
2. Baka, ayu, Alubosa elewe, apaokun, kanafuru, egbo ifon, ao
fi omi osan ati oti ibile lao fi re, ojo keta odi mimu

85. AGBO IBALOPO STD


#step to confirm
Chorophenical one sachet, ao po mo peak milk kan, ao ropo
immediately ko gbemu. Aaro ati ale fun 2 or 3days.

Agbore: bara kan, egbo oruwoo, epakun 4, baka 5, egbo


saworo, omidun laofise lagbo. Mimu laaro ati ale
86. OGUN TI EGUN OMODE O BALE ABIORUN E
KODURO
Egun eshin, aoko ewe omonigedegede, ewe kashew, ewe
iranje, ao ma fun omo na mu diedie ati wiwe
87. OGUN HYPERTENSIN (EJE RIRU)
Aowa ododo ori ako igi ibepe aodasinun omin tiwan bafise iru
aofi sibe fun 4days after 4days aomamun nin aro ati ale nigbati
aobafimun fun ojo meje pelu ase olorun yioti kuro nibe

You might also like