Ben Affleck
Ben Affleck | |
---|---|
Affleck ní ọdún 2017 | |
Ọjọ́ìbí | Benjamin Geza Affleck-Boldt[lower-alpha 1] 15 Oṣù Kẹjọ 1972 Berkeley, California, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | Occidental College |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1981–present |
Works | Full list |
Olólùfẹ́ | Àdàkọ:Plain list |
Àwọn ọmọ | 3 |
Àwọn olùbátan | Casey Affleck (brother) |
Awards | Full list |
Benjamin Géza Affleck[lower-alpha 2] (tí a bí ní ọjọ́ keedógún oṣù kẹjọ ọdún 1972) jẹ́ òṣèré àti aṣe fíìmù ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó tì gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Awards fún àwọn fíìmù rẹ̀. Affleck bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣeré láti ìgbà èwe nígbà tí ó ṣeré nínú eré PBS tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ The Voyage of the Mimi (1984, 1988). Ó tún padà ṣeré nínú Dazed and Confused (1993) àti àwọn eré àwàdà míràn tí Kevin Smith ṣe, àwọn eré bi Chasing Amy (1997).
Affleck tún gbajúmọ̀ si nígbà tí òun àti Matt Damon gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Award for Best Original Screenplay fún kíkọ Good Will Hunting (1997). Ó tún ṣeré nínú àwọn fíìmù bi Armageddon (1998), Pearl Harbor (2001), The Sum of All Fears àti Changing Lanes (both 2002). Lẹ́yìn ìgbà tí ó dàbí pé isẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré fẹ́ ma lọlẹ̀, ó tún padà sọ jí nígbà tí ó kó ipa George Reeves nínú fíìmù Hollywoodland (2006), ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ Volpi Cup for Best Actor.
Àwọn eré tí ó ti dárí ni Gone Baby Gone (2007), The Town (2010) àti Argo (2012).
Àwọn Ìtọ́kasí
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found
- ↑ White, Abbey (July 17, 2022). "Jennifer Lopez and Ben Affleck Announce Marriage". The Hollywood Reporter. Retrieved July 19, 2022.