Jump to content

Claire Trevor

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ẹ̀dà aṣeétẹ̀jáde kò ṣe é lò nínú, ó sì lè ní àṣìṣe àmúlò. Ẹ jọ̀ọ́, ẹ ṣe àtúnmúkójúùwọ̀n fún aṣèrántí-ojú-ìwé ẹ̀rọ-àṣàwárí, dákun, ṣàmúlò ìlò títẹ̀jáde ìpìlẹ̀ ti ẹ̀rọ-àṣàwárí dípò bẹ́ẹ̀.
Claire Trevor
Trevor in the 1930s
Ọjọ́ìbíClaire Wemlinger
(1910-03-08)Oṣù Kẹta 8, 1910
New York City, U.S.
AláìsíApril 8, 2000(2000-04-08) (ọmọ ọdún 90)
Newport Beach, California, U.S.
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1929–1987
Olólùfẹ́
  • Clark Andrews
    (m. 1938; div. 1942)
  • Cylos William Dunsmore
    (m. 1943; div. 1947)
  • Milton H. Bren
    (m. 1948; died 1979)
Àwọn ọmọ1

Claire Trevor ( Wemlinger; tí wọ́n bí ní Oṣù kẹ́ta Ọjọ́ kẹ́jọ, Ọdún 1910[1]tí ó sì fi ayé lẹ̀ ní oṣù kẹ́rin, ọdún 2000) jẹ́ Òsèré Amẹ́ríkà. Ó ṣe àfihàn rẹ̀ nínu fíìmù 65 feature láti ọdún 1933 títí di ọdún 1982,[2] tí ó jẹ́ kí ó gba ààwọ́ọ̀dù Academy Award for Best Supporting Actress fún ipa rẹ̀ ní Key Largo (1948), Wọ́n yọ̀hán fún ààwọ́ọ̀dù fún àwọn ìpò rẹ̀ ní àwọn eré The High and the Mighty (1954) àti Dead End (1937). Orúkọ Trevor ṣíwájú orúkọ John Wayne, fún Stagecoach (1939).

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ

Wọ́n bí Trevor ní Oṣù kẹ́ta Ọjọ́ kéje, ọdún 1910, níìlú Bensonhurst, Brooklyn,.Òun nìkan ni ọmọ fún Noel Wemlinger, Ònísòwò tálọ̀ (tí wọ́n bí níìlú faransé ṣùgbọ́n ní orírun ní Jamaní, àti ìyàwó rẹ̀ Benjamina ("Betty"), tí wọ́n bí níìlú Íírìṣì. Betty dàgbà sí New York City, àti láti ọdún 1923, ní Larchmont, New York.[3][4] Fún ọdún púpọ̀ ni ọjọ́ ìbí rẹ̀ jẹ́ àṣìsọ sí ọdún 1909, èyí ṣẹlẹ̀ nítorí wí pé ó kéré jù ọjọ́ orí ẹ̀ lọ lójú àwọn ènìyàn, fún ìdí èyí ló ṣe jẹ́ wí pé ọjọ́ orí tí wọ́n kọ́kọ́ sọ nígbà tó kú ní 91 tí kì í ṣe 90.[5]

Àwọn Ìtókasí

  1. Drew, William M. (1999). At the Center of the Frame: Leading Ladies of the Twenties and Thirties. Vestal Press. p. 319. ISBN 1-879511-42-8. ; Hagen, Ray; Laura Wagner (2004). Killer Tomatoes: Fifteen Tough Film Dames. McFarland. pp. 222. ISBN 0-7864-1883-4. ; Clara Wenlinger [sic], daughter of Noel and Benjamina, age 2 mos, is in the April 1910 Census of Brooklyn Ward 30, District 1054. This places her birth unambiguously in 1910.; "Actress Trevor dies at 90". The Charleston Gazette Associated Press. April 9, 2000. Archived from the original on August 5, 2017. https://web.archive.org/web/20170805103727/https://www.highbeam.com/doc/1P2-18564618.html. ;
  2. "A Hollywood Reputation : Claire Trevor Bren, known for playing strong if imperfect women, never achieved the stature of contemporaries Bette Davis or Joan Crawford, but she had other priorities. Family--including stepson and Irvine Co. Chairman Donald L. Bren--has always come first.". Los Angeles Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 1995-05-28. Retrieved 2022-03-18. 
  3. Sculthorpe, Derek (2018). Claire Trevor: The Life and Films of the Queen of Noir. Jefferson, N.C.: McFarland. p. 3. ISBN 9781476630694. https://books.google.com/books?id=zr5YDwAAQBAJ&pg=PA3. 
  4. Aronson, Steven M. L. (April 1992). "Claire Trevor's Glamorous Fifth Avenue Apartment". Architectural Digest. http://www.architecturaldigest.com/story/claire-trevor-fifth-avenue-apartment?story=A&subject=no. 
  5. "Claire Trevor, 91, Versatile Actress, Dies". The New York Times. 2000-04-10. https://query.nytimes.com/gst/fullpage.html?res=9C06EFDB163EF933A25757C0A9669C8B63. 

Àwọn ìtọ́kasí