Babayo Garba Gamawa
Ìrísí
Babayo Garba Gamawa | |
---|---|
aṣojú Àríwá Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2011 | |
Constituency | Àríwá Bauchi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Occupation | Oníṣòwò |
Profession | Olóṣèlú |
Babayo Garba Gamawa jẹ́ oníṣòwò àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Àríwá Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Babayo Garba Gamawa Homepage". Senator's Homepage.
- ↑ Abubakar, Muhammad. "Nigeria: Two Deputy Governors in Bauchi". AllAfrica. Retrieved 17 May 2012.
- ↑ Micheal, Ishola (1 July 2010). "Bauchi: A case of two sitting deputy govs". http://tribune.com.ng/index.php/politics/7592-bauchi-a-case-of-two-sitting-deputy-govs. Retrieved 17 May 2012.