Jump to content

Kwame Anthony Appiah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kwame Anthony Appiah
OrúkọKwame Anthony Appiah
Ìbí1954
ÌgbàContemporary philosophy
AgbègbèWestern Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Philosophy of Language, Cosmopolitanism
Ìjẹlógún ganganProbabilistic Semantics, Political Theory, Moral Theory, intellectual history, race and identity theory

Kwame Akroma-Ampim Kusi Anthony Appiah ( /ˈæpiɑː/ AP-ee-ah; tí a bí ní 8 May 1954) jẹ́ amòye, olùdámọ̀ràn nípa ọ̀rọ̀ àṣà, àti òǹkọ̀wé tó nífèẹ́ sí ọ̀rọ̀ ìṣèlú àti ìmòye ọlọ́gbọ́n. Appiah jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní Laurance S. Rockefeller University, Professor of Philosophy ní Princeton University,[1] kí ó tó kó lọ sí New York University (NYU) ní ọdún 2014.[2][3] Wọ́n fi Appiah joyè ààrẹ American Academy of Arts and Letters ní oṣù kìíní, ọdún 2022.[4]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


  1. "LAPA Faculty Associate: Kwame Anthony Appiah". lapa.princeton.edu. Program in Law and Public Affairs, Princeton University. Archived from the original on 3 June 2013. 
  2. Schuessler, Jennifer (26 November 2013). "Noted Philosopher Moves to N.Y.U. — and Beyond". The New York Times. http://artsbeat.blogs.nytimes.com/2013/11/26/noted-philosopher-moves-to-n-y-u-and-beyond/. 
  3. "NYU Law welcomes renowned philosopher Kwame Appiah to the faculty". law.nyu.edu. School of Law, NYU. 26 November 2013. 
  4. Weinberg, Justin (28 January 2022). "Appiah Named Next President of the American Academy of Arts and Letters". Retrieved 1 February 2022.