Philips Tanimu Aduda
Ìrísí
Philips Tanimu Aduda | |
---|---|
Aṣojú Abuja ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2011 sí 2015 | |
Asíwájú | Adamu Sidi Ali |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Karu, FCT Abuja, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Philips Tanimu Aduda jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Abuja, ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "FCT: Aduda, Ajulo, others battle for Senate seat". Nigerian Compass. 24 March 2011. Retrieved 2011-04-27.
- ↑ OMEIZA AJAYI (2011-04-11). "PDP maintains grip of FCT". National Mirror. Archived from the original on 2012-03-20. Retrieved 2011-04-27.