Nipa WordPress
Òpó ìtẹ̀jáde amúnáṣe ṣíṣí tí a yàn fún mílíọ̀nù àwọn ojú-ìwé káyè—láti àwọn olùdásílẹ̀ àti àwọn iṣẹ́ọ́wọ́ kékeré sí àwọn ilé-iṣẹ́ ńlá.
Apẹrẹ
Ṣẹ̀dá ojú-ìwé kankan pẹ̀lú àwọn irinṣẹ́ apẹrẹ onírọrùn àti agbára àwọn blọ́ọ̀kù. Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú kanfàsì aláìmọ̀ tàbí yàn àkọ́kọ́ ètò. Ṣe ìṣàtúnṣe gbogbo àkíyèsí—kò sí kóòdù nílò.
Kọ́
Wo bí ojú-ìwé rẹ yóò ṣe rí ní àkókò gan-an, ànígbà tí o ń fi, ṣàtúnṣe, àti ṣàtúnpọ̀ àkóónú—pẹ̀lú ìtúṣẹ̀ ìṣọ̀kan àti àwọn ẹ̀yà àfikún láti ṣàkóso rẹ̀ gbogbo.
Fà síwájú
Mú ojú-ìwé rẹ ṣe ohunkóhun tí o nílò. Fi ìṣọ́, àwọn ìṣirò, ìwé ìròyìn, ìsopọ̀ mẹ́díà àwùjọ; o ní ìṣàkóso pẹ̀lú ìkàwé tí ó ní àwọn ẹ̀rọ afúnni púpọ̀.
WordPress 7.1 mú ṣíṣe style
àti ṣíṣàtúnṣe rọrùn sí i
Ṣe àdáni àwọn block style ní ọ̀nà responsive kárí àwọn ìwọ̀n screen àti àwọn interactive state láìsí CSS. Media editor tó rọrùn tó fi àwọn irinṣẹ́ tó tọ́ sí iwájú, nígbà tí Notes ń ṣe àtìlẹ́yìn rich text àti @mentions báyìí. Admin bar náà tún máa wà pẹ̀lú rẹ kárí Site Editor àti block editor.
Platform kan, àgbáyé àwọn àǹfààní
Ṣàwárí àkójọpọ̀ àwọn àpẹẹrẹ ojúlé láti gbogbo àgbáyé, tí a ṣètò láti ṣàfihàn ìṣẹ̀dá tó lẹ́wà, ìdàgbàsókè ìmọ̀-ẹ̀rọ, àti agbára àìlópin WordPress.
Pàdé àwùjọ WordPress
Behind the technology is a diverse collective of people collaborating and gathering from around the world. We hold regular events with opportunities to learn more about WordPress and the latest tech trends, connect with fellow industry experts, and foster your professional growth.
A jẹ́ aláṣepọ̀ nípasẹ̀ ẹ̀mí amúnáṣe ṣíṣí, àti òmìnira láti kọ́, ṣíṣe àyípadà, àti pínpín láìsí ìdínà. Gbogbo ènìyàn ni a kí.
Kọ́ fún ara rẹ, kì í ṣe nípasẹ̀ ara rẹ nìkan
Yálà o jẹ́ oníṣòwò, developer ọ̀jọ̀gbọ́n, tàbí blogger àkọ́kọ́, ibi ìkówèéwé àwọn resource àti àwọn irinṣẹ́ ẹ̀kọ́ ti ṣetán fún ọ. Yàtọ̀ síyẹn, gbogbo àwùjọ WordPress wà lẹ́yìn rẹ.
Ìròyìn WordPress tuntun
Wọ Íńtánẹ́ẹ̀tì tí o ṣe
Bẹ̀rẹ̀
Wá gbogbo ohun tí o nílò láti bẹ̀rẹ̀, gba platform náà, wá hosting, àti sí i — yálà site àkọ́kọ́ rẹ ni tàbí site kọkàndínlọ́gọ́rùn-ún rẹ.