Jump to content

Lucrécia Paco

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àtúnyẹ̀wò ní 04:59, 25 Oṣù Òwéwe 2023 l'átọwọ́ InternetArchiveBot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
(ìyàtọ̀) ← Àtúnyẹ̀wò tópẹ́ju | Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí (ìyàtọ̀) | Àtúnyẹ̀wò tótuntunju → (ìyàtọ̀)
Lucrécia Paco
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kẹ̀wá 1969 (1969-10-19) (ọmọ ọdún 55)
Maputo, Mozambique
Orílẹ̀-èdèMozambican
Iṣẹ́osere
Ìgbà iṣẹ́1984-titi di isinyi

Lucrécia Paco (ti a bi ni ojo kankandilogun osu kewa odun 1969) je osere ti o wa lati ilu Mozambique. O je okan larin awon osere ti oniyi ju ni Mozambique.

Paco dagba ni Maputo. Ni igba ti owa ni omode, o feran ki oma ko orin ati ki o ma jo si awon orin ibile, eleyi ti ko po nita ki Mozambique to gba ominira ni odun 1975. Ko da wan Paco ni ile iwe nitori o man so ede ibile. Lehin ominira awon egbe sosialisiti gba won ni iyanju ki won ma se ere itage ati bebelo, Paco si kopa ninu ijo, orin ati ewi kika.[1]

Ni asiko Ogun abele Mozambique, Paco fi akiyesi eh si ara ere itage gege bi ise oselu. O ko ipa ninu ere itan titi 1984 Maputo Mulher.[2] Ni odun 1986 Paco wa lara awon oludasile Mutumbela Gogo troupe, egbe ere itage akoko ni Mozambique, ti osi wa di eni. Awon ere Soviet ti owo lo wu lori lofi se awon ere kukuru nipa bi o se ri ki eyan ma gbe ni Mozambique. Ki won ba le se olugbowo egbe ere itage na, won ko ile ise buredi.[3]

Paco fun ra e ni isnmi odun marun nitori pe o re[4] Ni odun 2009 Instituto Itaú Cultural pe Paco wa si ilu Brasil. O ko ipa ninu project antidote pelu ere Mulher Asfalto.[5] Ni odun 2009 mu Paco gege bi olukopa ninu ere Quero Ser uma Estrela. Lehin igba na oko ipa kan ninu Nineteens ere Telenovela akoko titi Mozambique.

Odun Akori Ipa
2010 Nineteens Glória Monjane
2002 A Jóia de África Abibi
Year Title Role
2010 Quero Ser uma Estrela Obinrin[6]
2010 Flores Silvestres [7]
1998 Nelio's Story Maria[8]
1986 O Vento Sopra do Norte
1984 Maputo Mulher
  1. Gomes, Christiane (September 2011). "LUCRÉCIA PACO E O TEATRO COMO FERRAMENTA DE TRANSFORMAÇÃO SOCIAL" (in Portuguese). Omenelick. Archived from the original on 26 November 2013. Retrieved 8 October 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Lucrecia Paco". Club of Mozambique. 5 July 2016. Retrieved 8 October 2020. 
  3. Gomes, Christiane (September 2011). "LUCRÉCIA PACO E O TEATRO COMO FERRAMENTA DE TRANSFORMAÇÃO SOCIAL" (in Portuguese). Omenelick. Archived from the original on 26 November 2013. Retrieved 8 October 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Pila, Elton. "Lucrécia paco:Uma vida em que cabem muitas vidas". Literatas. Archived from the original on 16 October 2020. Retrieved 8 October 2020. 
  5. Gomes, Christiane (September 2011). "LUCRÉCIA PACO E O TEATRO COMO FERRAMENTA DE TRANSFORMAÇÃO SOCIAL" (in Portuguese). Omenelick. Archived from the original on 26 November 2013. Retrieved 8 October 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. http://omelete.uol.com.br/filmes/quero-ser-uma-estrela/elenco/
  7. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-02-01. Retrieved 2020-10-17. 
  8. http://www.cineplex.com/Movie/comedia-infantil

Awọn ọna asopọ ita

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]