Adolf Hitler
Ìrísí
Adolf Hitler | |
---|---|
20 April 1937 (48th Birthday) | |
Führer of Germany | |
In office 2 August 1934 – 30 April 1945 | |
Asíwájú | Paul von Hindenburg (as President) |
Arọ́pò | Karl Dönitz (as President) |
Reichskanzler (Chancellor) of Germany | |
In office 30 January 1933 – 30 April 1945 | |
Asíwájú | Kurt von Schleicher |
Arọ́pò | Joseph Goebbels |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 20 April 1889 Braunau am Inn, Austria–Hungary |
Aláìsí | 30 April 1945 Berlin, Germany | (ọmọ ọdún 56)
Cause of death | Suicide |
Aráàlú | Austrian (1889–1932) German (1932–1945) |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Austrian citizen until 1925[1] German citizen after 1932 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National Socialist German Workers Party (NSDAP) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Eva Braun (married on 29 April 1945) |
Occupation | politician, soldier, artist, writer |
Awards | Iron Cross First and Second Class Wound Badge |
Signature | |
Military service | |
Allegiance | German Empire |
Branch/service | Reichsheer |
Years of service | 1914–1918 |
Rank | Gefreiter |
Unit | 16th Bavarian Reserve Regiment |
Battles/wars | World War I |
Adolf Hitler (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈadɔlf ˈhɪtlɐ]; 20 April 1889 – 30 April 1945) je omo Jemani ti a bi ni Austria to je oloselu ati olori Egbe awon Osise Sosialisti Tomoorile-ede Jemani (, kikekuru bi NSDAP), to gbajumo bi Egbe Nazi. O je Kansilo ile Jemani lati 1933 de 1945 besini leyin 1934, gege bi olori orile-ede bi Führer und Reichskanzler, o si joba ibe bi apase wa.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Hitler ersucht um Entlassung aus der österreichischen Staatsangehörigkeit", 7 April 1925 (Jẹ́mánì). Translation: "Hitler's official application to end his Austrian citizenship". NS-Archiv. Retrieved on 2008-08-19
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Adolf Hitler |