Bianca Andreescu
Ìrísí
Andreescu in 2015 | |
Orílẹ̀-èdè | Canada |
---|---|
Ibùgbé | Thornhill, Ontario, Canada[1] |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kẹfà 2000 Mississauga, Ontario, Canada |
Ìga | 1.70 m |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 2017 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Olùkọ́ni | Sylvain Bruneau |
Ẹ̀bùn owó | US$6,720,038 |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 137–50 (73.26%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 3 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 4 (28 October 2019) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 6 (9 March 2020) |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | 2R (2019) |
Open Fránsì | 2R (2019) |
Wimbledon | 1R (2017) |
Open Amẹ́ríkà | W (2019) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje WTA | RR (2019) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 29–16 (64.44%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 0 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 147 (16 July 2018) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 1214 (3 February 2020) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Amẹ́ríkà | 1R (2019) |
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò | |
Fed Cup | PO (2019) |
Last updated on: 3 February 2020. |
Bianca Vanessa Andreescu (Àdàkọ:IPA-ro; ọjọ́ìbí June 16, 2000) ni agbá tẹ́nìs ará Kánádà. Ipò rẹ̀ lágbààyé tó gajùlọ ni No. 4, òhun ni ará Kánádà tí ipò rẹ̀ gajùlọ láti ìbẹ̀rẹ̀ àjọ Women's Tennis Association (WTA). Andreescu gba ife-ẹ̀yẹ Open Amẹ́ríkà 2019 àti ife-ẹ̀yẹ Open Kánádà 2019 nígbà tó borí Serena Williams ní ìparí ìdíje mẹ́jẹ́èjì.
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Bianca Andreescu". WTA Tennis. Retrieved September 6, 2019.