Nestlé
Ìrísí
Nestlé S.A. (ìpè Faransé: [nɛsle]; English: /ˈnɛsleɪ, ˈnɛsəl, ˈnɛsli/English /ˈnɛsleɪ,_ˈnɛsəl,_ˈnɛsli/, tì a mó télè si: /ˈnɛsəlz/ /ˈnɛsəlz/) jẹ́ ilé-iṣẹ̀ aṣońjẹ ti orílè-èdè Swiss, tí olú-iléesé wọn wà ní Vevey, Vaud, Switzerland. Ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ asońje tí ó tóbi jùlo ní àgbáyé bí a bá fi òṣùwòn owó pípa wolé àti awon òṣùẁòn mìíràn láti ọdún 2014.[1][2][3][4][5] [6]
Ọ̀rọ̀ lórí àwọn ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Nestlé's Brabeck: We have a "huge advantage" over big pharma in creating medical foods", CNN Money, 1 April 2011
- ↑ "Nestlé: The unrepentant chocolatier", The Economist, 29 October 2009. Retrieved 17 May 2012
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)