Jump to content

Peter Sarsgaard

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Peter Sarsgaard
Sarsgaard ní òṣù kẹsán án ọdún 2019
Ọjọ́ìbíJohn Peter Sarsgaard
7 Oṣù Kẹta 1971 (1971-03-07) (ọmọ ọdún 53)
St. Clair County, Illinois, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaWashington University in St. Louis
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1995–present
Olólùfẹ́
Àwọn ọmọ2
Àwọn olùbátanJake Gyllenhaal (brother-in-law)

John Peter Sarsgaard ( /ˈsɑrzɡɑrd/; tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1971) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ṣeré fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú eré Dead Man Walking ní ọdún 1995. Ó tún ṣeré nínú fíìmù independent tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Another Day in Paradise àti nínú Desert Blue. Ní ọdún kan náà, Sarsgaard kópa Raoul nínú eré The Man in the Iron Mask (1998). Sarsgaard padà di gbajúmọ̀ nígbà tí ó kópa John Lotter nínú eré Boys Don't Cry (1999).

Fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Charles Lane nínú erẹ́ Shattered Glass, wọ́n yan Sarsgaard mọ́ ara àwọn tí ó tọ́sí àmì-ẹ̀yẹ Golden Globe Award for Best Supporting Actor. Sarsgaard ti ṣeré nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré, bí àpẹẹrẹ: K-19: The Widowmaker (2002), Garden State, Kinsey (both 2004), Jarhead (2005), Flightplan (2005), Elegy (2008), An Education (2009), Lovelace (2013), Night Moves (2013), Blue Jasmine (2013), Black Mass (2015), Jackie (2016), àti The Lost Daughter (2021). Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú àwọn eré Green Lantern (2011), Knight and Day (2010), The Magnificent Seven (2016) àti The Batman (2022).