John Okechukwuemeka
Ìrísí
John Okechukwuemeka | |
---|---|
Mínísítà ìpínlẹ̀ tẹ́lẹ̀ fún ètò ìgbòkègbodò ọkọ̀ | |
In office Oṣù keje Ọdún 2007 – Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹwá Ọdún 2008 | |
Aṣojú Àríwá Ìpínlẹ̀ Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù karún Ọdún 2011 | |
Asíwájú | Alphonsus Obi Igbeke |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Keje 1962 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
John Okechukwuemeka jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó jẹ́ mínísítà ìpínlẹ̀ tẹ́lẹ̀ fún ètò ìgbòkègbodò ọkọ̀ tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Àríwá Ìpínlẹ̀ Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà látàrí ètò ìdìbò ti Oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Collated Senate results". INEC. Archived from the original on 2011-04-19. Retrieved 2011-05-04.
- ↑ "New List of Federal Ministers of Nigeria & Their Ministries - After Yar'Adua Drops 20 Ministers.". Nigerian Muse. October 29, 2008. Retrieved 2011-05-04.